Skip to main content

Intafeesi Olumulo ti Ayelujara

Uplinks

Verdaccio ni intafeesi olumulo ayelujara kan lati safihan awọn akopọ aladani naa nikan atipe o le jẹ sise ni akanṣe.

web:
enable: true
title: Verdaccio
logo: logo.png
primary_color: "#4b5e40"
gravatar: true | false
scope: "@scope"
sort_packages: asc | desc

Gbogbo awọn idena wiwọle ti o jẹ sisetodabobo awọn akopọ rẹ naa yoo jẹ sisamulo si Intafeesi Ayelujara naa.

O jẹ igbaniyanju pe ki iwọn aami idanimọ ni iwọn wọnyii 40x40 pixels.

The primary_color must be a valid hex representation.

Internationalization

Since v4.5.0, there are translations available.

i18n:
web: en-US

⚠️ Only the languages in this list are available, feel free to contribute with more. The default one is en-US

Configuration

Ohun iniIruTi o niloApẹẹrẹAtilẹyinApejuwe
muṣiṣẹbooleanRaraotitọ/irọgbogbogba lati ṣafihan intafeesi ayelujara naa
akọleokunRaraVerdacciogbogboApejuwe akọle akori HTML
gravatarbooleanRaraotitọ>v4Gravatars yoo jẹ pipilẹṣẹ labẹ ibori ti o ba jẹ pe ohun-ini yii wa ni imusisẹ
sort_packages[asc,desc]Raraasc>v4Nipa atilẹwa awọn akopọ aladani ti jẹ siseto lẹsẹsẹ ni ọna igasoke
logookunRara/local/path/to/my/logo.png http://my.logo.domain/logo.pnggbogbouRI kan nibi ti aami idanimọ wa (akọle aami idanimọ)
primary_colorokunRara"#4b5e40">4Awọ akọkọ lati lo jakejado UI naa(akọle, abbl)
scopeokunRara@myscope>v3.xTi o ba n lo iforukọsilẹ yii fun scope modulu kan ni pato, yan scope naa lati ṣeto rẹ ninu akọle itọnisọna webui
darkModebooleanRarafalse>=v4.6.0This mode is an special theme for those want to live in the dark side
faviconokunRarafalse>=v5.0.1Display a custom favicon, can be local resource or valid url

The recommended logo size is 40x40 pixels.

The darkMode can be enabled via UI and is persisted in the browser local storage. Furthermore, also void primary_color and dark cannot be customized.