Skip to main content

Awọn Iṣẹ Ayelujara ti Amazon

Iwe yii n ṣe apejuwe awọn orisirisi ọna fun sisẹ amulo Verdaccio ni ipamọ ayelujara ti AWS.

EC2

Awoṣe CloudFormation fun ṣiṣe amulo eto akopọ yii.

Iyaworan:

Clients
|
| (HTTPS)
v
Application Load Balancer
|
| (HTTP)
v
EC2 Auto Scaling Group (Amazon Linux 2)
Docker image (Verdaccio)
|
| (NFS)
v
Elastic File System

Awọn akọsilẹ Iyaworan: * Ṣe amulo eto akopọ yii si agbegbe ti o sunmọ julọ fun awọn olumulo rẹ fun iṣẹ to peye julọ. * A lo akojọpọ ti o ni ipele agbara alaifọwọyi nipataki fun imularada alara-ẹni. Awọn inilo eto ti Verdaccio kere jọjọ, nitorina o sọwọn pe o ma nilo awọn isẹlẹ pupọ lati mojuto ẹru abẹwo. * Nitoripe Amazon Linux 2 ko ni Oju ipade, a n lo Verdaccio gẹgẹbi aworan Docker dipo ilo abinibi lori isẹlẹ. Eleyi tubọ yara si ati tubọ ni aabo sii ju gbigbe ara le awọn orisun akojọ ti alagata lọ fun Oju ipade. * Eto Faili Oniriran jẹ olowo pọku ati oniranti ipo ibasepọ, atipe o n ṣiṣẹ jakejado AZs. Ọna miiran yoo jẹ ti ohun-elo ipamọ S3 ti alagata. * Fun atilẹyin, lo Atilẹyin AWS

 • Deploy this stack into the region closest to your users for maximum performance.
 • We use an auto scaling group primarily for self-healing. The system requirements of Verdaccio are pretty low, so it's unlikely you'll need multiple instances to handle traffic load.
 • Because Amazon Linux 2 doesn't include Node, we run Verdaccio as a Docker image rather than natively on the instance. This is faster and more secure than relying on third party package sources for Node.
 • Elastic File System is cheap and stateful, and works across AZs. An alternative would be the third-party S3 storage plugin.
  • For backup, use AWS Backup

Afojuda iye owo osoosu fun igbekalẹ kekere kan (ni us-east-1): * ALB (agbede 1 LCU): $22.265/osu * EC2 (t3.nano): $3.796/osu * EBS (8gb): $0.80/osu * EFS (5gb): $1.5/osu * Data transfer: (10gb): $0.9/osu * APAPỌ: Koju $30/osu lọ

 • ALB (1 LCU average): $22.265/mo
 • EC2 (t3.nano): $3.796/mo
 • EBS (8gb): $0.80/mo
 • EFS (5gb): $1.5/mo
 • Data transfer: (10gb): $0.9/mo
 • TOTAL: Under $30/mo

ECS

O le ṣe amulo Verdaccio bi iṣẹ pẹlu ECS Volume fun ibi ipamọ alatẹnumọ.

Akiyesi: Fargate ko ṣe atilẹyin fun awọn iwọn iye alatẹnumọ, nitorina o ni lati lo ohun elo ipamọ S3.

EKS

Wo awọn oju ewe iwe lori Kubernetes ati Docker.