Fifi sori ẹrọ Bi Iṣẹ Windows kan
O da lori awọn itọnisọna ti o wa nibi. Mo ṣẹda iwọnyi ti o si wa pese iṣẹ verdaccio ti o n ṣiṣẹ ni kikun fun mi:
- Ṣẹda ọna fun verdaccio
- mkdir
c:\verdaccio
- cd
c:\verdaccio
- mkdir
- Fi verdaccio sori ẹrọ ni ibilẹ (Mo salaba pade awọn iṣoro npm pẹlu awọn fifisori ti agbaye)
- npm install verdaccio
- Ṣẹda faili
config.yaml
rẹ ni aaye yii(c:\verdaccio\config.yaml)
- Iṣeto Iṣẹ Windows
Lilo NSSM
ỌNA MIRAN: (Akopọ WinSW ti sọnu nigbati mo gbiyanju lati gba lati ayelujara)
Gba NSSM ki o si fa jade
Se afikun ọna ti o ni nssm.exe si PATH
Ṣi aṣẹ isakoso kan
Ṣe imuṣiṣẹ nssm install verdaccio Ni o kere ju o gbọdọ pese idahun si Ọna taabu Ohun elo, Ibẹrẹ ọna ati Awọn aaye awọn ariyanjiyan. Kani wipe ifisori ẹrọ pẹlu oju ipade ninu ọna eto naa ati aaye kan ti c:\verdaccio awọn iye to wa ni isalẹ yoo ṣiṣẹ:
- Path:
node
- Startup directory:
c:\verdaccio
- Awọn ariyanjiyan:
c:\verdaccio\node_modules\verdaccio\build\lib\cli.js -c c:\verdaccio\config.yaml
O le ṣatunṣe awọn iseto iṣẹ miiran labẹ awọn taabu miiran bi o ba se fẹ. Nigbati o ba ti ṣetan, tẹ bọtini Fi iṣẹ sori ẹrọ
- Bẹrẹ iṣẹ sc naa bẹrẹ verdaccio
- Path:
Lilo WinSW
- Titi di 2015-10-27, WinSW ko si ni aaye to wa ni isalẹ yii mọ. Jọwọ tẹle awọn ilana itọnisọna Lilo NSSM loke.
- Gba lati ayelujara WinSW
- Gbe awọn iṣẹ ṣiṣe naa (fun apẹẹrẹ
winsw-1.9-bin.exe
) sinu foda yii (c:\verdaccio
) ki o si pa lorukọ da siverdaccio-winsw.exe
- Gbe awọn iṣẹ ṣiṣe naa (fun apẹẹrẹ
- Ṣẹda faili iṣeto kan ni
c:\verdaccio
, ti o n jẹverdaccio-winsw.xml
pẹlu iṣeto wọnyiixml verdaccio verdaccio verdaccio node c:\verdaccio\node_modules\verdaccio\src\lib\cli.js -c c:\verdaccio\config.yaml roll c:\verdaccio
. - Fi iṣẹ rẹ sii
cd c:\verdaccio
verdaccio-winsw.exe install
- Bẹrẹ iṣẹ rẹ
verdaccio-winsw.exe start
Diẹ lara awọn iṣeto ti o wa loke jẹ verbose ju bi mo ti se reti lọ, o dabi pe 'workingdirectory' ti ko bikita, ṣugbọn yatọ si eyi, eyi ṣiṣẹ fun mi o si fayegba verdaccio instance mi lati si duro sinsin laarin atunbẹrẹ ti olupese naa, ati sise atunbẹrẹ ara rẹ ti o ba lọ jẹpe ijamba kankan ba waye si ilana verdaccio naa.