Verdaccio

Verdaccio

  • Awọn iwe
  • Bulọọgi
  • Twitter
  • Iranlọwọ
  • GitHub
  • Contributors
  • Sponsor Us
  • Languages iconYoruba
    • English
    • Español
    • Français
    • 中文
    • Russian
    • Pese iranlọwọ lati Tumọ

›Olupese

Ifihan

  • Ki ni verdaccio?
  • Ifi sori ẹrọ
  • Irinṣẹ Ila aṣẹ
  • Using a private registry
  • Tani o nlo Verdaccio?
  • Eto imulo Aabo
  • Irulogo
  • Uses Cases

    • Idanwo Opin si Opin
    • Awọn ọna ifisapo iranti
    • GitHub Actions
    • Sise asopọ ibi iforukọsilẹ ọlọna jijin kan

    Talks & Articles

    • Awọn arokọ
    • Awọn ọrọ

Ẹya ara

  • Faili Iṣeto
  • Uplinks
  • Iwọlesi Akopọ
  • Ifasẹsi
  • Awọn ifitonileti
  • Olugbasilẹ
  • Intafeesi Olumulo ti Ayelujara

Olupese

  • Iṣeto Olupese
  • Iseto Aṣoju ikọkọ-Alayipada
  • Ṣeto Awọn iwe ẹri SSL
  • Fifi sori ẹrọ Bi Iṣẹ Windows kan
  • Fifi sori olupese IIS

Agbedide

  • Awọn ohun elo
  • Ṣiṣe agbedide Awọn ohun elo
  • Dev Guides

    • Plugin Generator
    • Ohun elo Ifasẹsi
    • Ohun elo Middleware
    • Ohun elo Ibi ipamọ
  • API Oju ipade

DevOps

  • Docker
  • Kubernetes
  • Imuṣiṣẹpọ Alainidaduro
  • Cloud

    • Awọn Iṣẹ Ayelujara ti Amazon

    Tools

    • Ansible
    • Puppet
    • Iwe idana Alase

Awọn itọsọna

  • Awọn iṣeṣi to Darajulọ
  • Didabobo awọn akopọ
  • Awọn Iṣẹ Ayelujara ti Amazon
Translate

Ṣeto Awọn iwe ẹri SSL

Follow these instructions to configure an SSL certificate to serve an npm registry over HTTPS.

  • Ṣe imudojuiwọn ohun elo itẹtisi ni ~/.config/verdaccio/config.yaml rẹ:

    listen: 'https://your.domain.com/'

Lọgan ti o ti se imudojuiwọn ohun elo itẹtisi ati gbigbiyanju lati ṣe imuṣiṣẹ verdaccio lẹẹkansi, yoo beere fun awọn iwe ẹri.

  • Pilẹṣẹ awọn iwe ẹri rẹ

    $ openssl genrsa -out /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-key.pem 2048 $ openssl req -new -sha256 -key /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-key.pem -out /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-csr.pem $ openssl x509 -req -in /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-csr.pem -signkey /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-key.pem -out /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-cert.pem

    
    * Ṣatunkọ faili iṣeto rẹ `/Users/user/.config/verdaccio/config.yaml` ki o si se afikun abala wọnyi:
    
    
    
    

https: key: /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-key.pem cert: /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-cert.pem ca: /Users/user/.config/verdaccio/verdaccio-csr.pem

<br />Ni ọna miiran, ti o ba ni iwe ẹri pẹlu ilana ti `server.pfx`, o le se afikun awọn abala iṣeto wọnyii: (Gbolohun irekọja naa kii se dandan ati pe o ma jẹ ni nilo nikan to ba jẹ pe iwe ẹri rẹ jẹ alaroko.)

https: pfx: /Users/user/.config/verdaccio/server.pfx passphrase: 'secret' ````

O le ri alaye diẹ sii lori awọn ariyanjiyan key, cert, ca, pfx, ati passphrase ni Iwe akọsilẹ Oju ipade

  • Se imusisẹ verdaccio ninu ila aṣẹ rẹ.

  • Ṣii ẹrọ aṣàwákiri ayelujara ki o si ṣabẹwo si https://your.domain.com:port/

Awọn itọsọna wọnyi ma n saba fẹsẹmulẹ labẹ OSX ati Linux; lori Windows awọn ọna naa yoo yatọ, ṣugbọn awọn igbesẹ naa jẹ bakanna.

Docker

Ti o ba n lo aworan Docker, o ni lati ṣeto iyipada ayika VERDACCIO_PROTOCOL si https, gẹgẹ bi ariyanjiyan listen se jẹ pipese ninu Dockerfile naa ati pe o foju fo ti inu faili iṣeto rẹ.

O tun le ṣeto iyipada ayika VERDACCIO_PORT ti o ba nlo ibudo miiran to yatọ si 4873.

← Iseto Aṣoju ikọkọ-AlayipadaFifi sori ẹrọ Bi Iṣẹ Windows kan →
  • Docker
Verdaccio
Docs
Getting StartedDockerConfigurationLogos
Community
User ShowcaseStack OverflowProject ChatFollow Verdaccio on Twitter
More
BlogGitHubStar