Verdaccio

Verdaccio

  • Awọn iwe
  • Bulọọgi
  • Twitter
  • Iranlọwọ
  • GitHub
  • Contributors
  • Sponsor Us
  • Languages iconYoruba
    • English
    • Español
    • Français
    • 中文
    • Russian
    • Pese iranlọwọ lati Tumọ

›Ẹya ara

Ifihan

  • Ki ni verdaccio?
  • Ifi sori ẹrọ
  • Irinṣẹ Ila aṣẹ
  • Using a private registry
  • Tani o nlo Verdaccio?
  • Eto imulo Aabo
  • Irulogo
  • Uses Cases

    • Idanwo Opin si Opin
    • Awọn ọna ifisapo iranti
    • GitHub Actions
    • Sise asopọ ibi iforukọsilẹ ọlọna jijin kan

    Talks & Articles

    • Awọn arokọ
    • Awọn ọrọ

Ẹya ara

  • Faili Iṣeto
  • Uplinks
  • Iwọlesi Akopọ
  • Ifasẹsi
  • Awọn ifitonileti
  • Olugbasilẹ
  • Intafeesi Olumulo ti Ayelujara

Olupese

  • Iṣeto Olupese
  • Iseto Aṣoju ikọkọ-Alayipada
  • Ṣeto Awọn iwe ẹri SSL
  • Fifi sori ẹrọ Bi Iṣẹ Windows kan
  • Fifi sori olupese IIS

Agbedide

  • Awọn ohun elo
  • Ṣiṣe agbedide Awọn ohun elo
  • Dev Guides

    • Plugin Generator
    • Ohun elo Ifasẹsi
    • Ohun elo Middleware
    • Ohun elo Ibi ipamọ
  • API Oju ipade

DevOps

  • Docker
  • Kubernetes
  • Imuṣiṣẹpọ Alainidaduro
  • Cloud

    • Awọn Iṣẹ Ayelujara ti Amazon

    Tools

    • Ansible
    • Puppet
    • Iwe idana Alase

Awọn itọsọna

  • Awọn iṣeṣi to Darajulọ
  • Didabobo awọn akopọ
  • Awọn Iṣẹ Ayelujara ti Amazon
Translate

Faili Iṣeto

This file is the cornerstone of Verdaccio where you can modify the default behaviour, enable plugins and extend features.

Faili iṣeto atilẹwa kan config.yaml jẹ ṣiṣẹda ni igba akọkọ ti o ba ṣe amulo verdaccio.

Iṣeto Atilẹwa

The default configuration has support for scoped packages and allows any user to access all packages, but only authenticated users to publish.

storage: ./storage
auth:
  htpasswd:
    file: ./htpasswd
uplinks:
  npmjs:
    url: https://registry.npmjs.org/
packages:
  '@*/*':
    access: $all
    publish: $authenticated
    proxy: npmjs
  '**':
    proxy: npmjs
logs:
  - {type: stdout, format: pretty, level: http}

Awọn abala

The following sections explain what each property means and their different options.

Ibi ipamọ

Ni aaye ibi ipamọ atilẹwa. Verdaccio ni atilẹwa da lori eto faili ibilẹ.

storage: ./storage

Awọn ohun elo

Is the location of the plugin directory. Useful for Docker/Kubernetes-based deployments.

plugins: ./plugins

Ifasẹsi

The authentication setup is done here. The default auth is based on htpasswd and is built in. You can modify this behaviour via plugins. For more information about this section read the auth page.

auth:
  htpasswd:
    file: ./htpasswd
    max_users: 1000

Aabo

Niwọn: verdaccio@4.0.0 #168

Bulọọku aabo fayegba ọ lati ṣe aami ibuwọlu naa ni akanṣe. To enable a new JWT (JSON Web Tokens) signature you need to add the block jwt to the api section; web uses jwt by default.

Iṣeto naa jẹ pinpin si abala meji, api ati web. To use JWT on api it has to be defined, otherwise the legacy token signature (aes192) will be used. For JWT you might want to customize the signature and the token verification with your own properties.

security:
  api:
    legacy: true
    jwt:
      sign:
        expiresIn: 29d
      verify:
        someProp: [value]
   web:
     sign:
       expiresIn: 7d # 7 days by default
     verify:
        someProp: [value]

A ṣe igbaniyanju to ga lati ko lọ si JWT niwọnti ibuwọlu ijogun (aes192) ti wa ni iparun ati pe o ma farasin ni awọn ẹya ọjọ iwaju.

Olupese

Awọn eto ohun elo lati ṣe ayipada iwa ti ohun elo olupese naa, paapaa API (Express.js).

O le ṣe olupese HTTP / 1.1 ni pato pe ki o ma ṣe itọju iwalaye akoko idawọduro ni iṣẹju aaya fun awọn isopọ ti o n wọle. Iye kan ti o jẹ 0 n mu ki olupese http ma huwa to jẹmọ ti awọn ẹya Node.js ṣiwaju si 8.0.0, eyi ti ko ni itọju iwalaye akoko idawọduro. ỌNA ABAYỌ: Nipasẹ iṣeto ti a fun ọ o le ri ọgbọn da si awọn iṣoro yii https://github.com/verdaccio/verdaccio/issues/301. Ṣeto rẹ si 0 nitori ti 60 ko ba to.

server:
  keepAliveTimeout: 60

UI Ayelujara

This property allow you to modify the look and feel of the web UI. For more information about this section read the web UI page.

web:
  enable: true
  title: Verdaccio
  logo: logo.png
  scope:

Uplinks

Uplinks add the ability to fetch packages from remote registries when those packages are not available locally. For more information about this section read the uplinks page.

uplinks:
  npmjs:
    url: https://registry.npmjs.org/

Awọn akopọ

This section allows you to control how packages are accessed. For more information about this section read the packages page.

packages:
  '@*/*':
    access: $all
    publish: $authenticated
    proxy: npmjs

Iṣeto Giga

Atẹjade Alaisilorila

By default verdaccio does not allow you to publish packages when the client is offline. This can be can be overridden by setting this value to true.

publish:
  allow_offline: false

Niwọn: verdaccio@2.3.6 nitori #223

Ibẹrẹ URL

url_prefix: /verdaccio/

A ṣe igbaniyanju pe ki o lo ipin-ọna kan /verdaccio/ dipo URI kan.

Iwọn Ara to Pọju

By default the maximum body size for a JSON document is 10mb, if you run into errors that state "request entity too large" you may increase this value.

max_body_size: 10mb

Ibudo Itẹtisi

verdaccio runs by default on the port 4873. Changing the port can be done via CLI or in the configuration file. The following options are valid:

listen:
# - localhost:4873            # default value
# - http://localhost:4873     # same thing
# - 0.0.0.0:4873              # listen on all addresses (INADDR_ANY)
# - https://example.org:4873  # if you want to use https
# - "[::1]:4873"                # ipv6
# - unix:/tmp/verdaccio.sock    # unix socket

HTTPS

Lati mu https ṣiṣẹ ninu verdaccio o to lati ṣeto asia listen pẹlu Ilana https://. For more information about this section read the SSL page.

https:
    key: ./path/verdaccio-key.pem
    cert: ./path/verdaccio-cert.pem
    ca: ./path/verdaccio-csr.pem

Aṣoju ikọkọ

Awọn aṣoju ikọkọ jẹ awọn olupese HTTP oniṣẹ-pataki ti o jẹ didalara lati gbe data kuro lati awọn olupese ọlọna jinjin lọ si awọn onibara agbegbe.

http_proxy ati https_proxy

If you have a proxy in your network you can set a X-Forwarded-For header using the following properties:

http_proxy: http://something.local/
https_proxy: https://something.local/

no_proxy

This variable should contain a comma-separated list of domain extensions that the proxy should not be used for.

no_proxy: localhost,127.0.0.1

Awọn ifitonileti

Enabling notifications to third-party tools is fairly easy via webhooks. For more information about this section read the notifications page.

notify:
  method: POST
  headers: [{'Content-Type': 'application/json'}]
  endpoint: https://usagge.hipchat.com/v2/room/3729485/notification?auth_token=mySecretToken
  content: '{"color":"green","message":"New package published: * {{ name }}*","notify":true,"message_format":"text"}'

Fun alaye awọn eto iṣeto siwaju sii, jọwọ ṣayẹwo koodu orisun naa.

Ayẹwo

Lati: verdaccio@3.0.0

ayẹwo npmt jẹ aṣẹ tuntun kan ti o jẹ pipese pẹlu npm 6.x. Verdaccio wa pẹlu ohun elo middleware ti o jẹ kikọ sinu rẹ lati sakoso aṣẹ yii.

Ti o ba sẹsẹ fi sori ẹrọ o ma n ba wa ni atilẹwa, bibẹkọ o nilo lati se afikun awọn atilẹyin wọnyi sinu faili iṣeto rẹ

middlewares:
  audit:
    enabled: true

Experiments

This release includes a new property named experiments that can be placed in the config.yaml and is completely optional.

We want to be able to ship new things without affecting production environments. This flag allows us to add new features and get feedback from the community who decides to use them.

The features under this flag might not be stable or might be removed in future releases.

Here is one example:

experiments:
  token: false

To disable the experiments warning in the console, you must comment out the whole experiments section.

← Awọn ọrọUplinks →
  • Iṣeto Atilẹwa
  • Awọn abala
    • Ibi ipamọ
    • Awọn ohun elo
    • Ifasẹsi
    • Aabo
    • Olupese
    • UI Ayelujara
    • Uplinks
    • Awọn akopọ
  • Iṣeto Giga
    • Atẹjade Alaisilorila
    • Ibẹrẹ URL
    • Iwọn Ara to Pọju
    • Ibudo Itẹtisi
    • HTTPS
    • Aṣoju ikọkọ
    • Awọn ifitonileti
    • Ayẹwo
    • Experiments
Verdaccio
Docs
Getting StartedDockerConfigurationLogos
Community
User ShowcaseStack OverflowProject ChatFollow Verdaccio on Twitter
More
BlogGitHubStar